Submit your work, meet writers and drop the ads. Become a member
Impulzez Jul 2016
Eni tanfe la ni
eni tani la nfe

iwo mo fe tokan mi fe
iwo mi ni tonje kinma mi

Afuruginaya
Afuruginaya

ina sonki
ina sonka

Ohun ti o gan iye ni ohun ti
o padanu, ko ohun ti o ni

mo ni ikan ti mo fe
mo ni ikan ti mo fe

@joecuji
What you really value is what you miss, not what it is
Tauhid May 2016
b'ęránko bà p'égbá nigbò, kiniun lolori wøn
b'ęiyę p'øgøfa l'ødan așa l'øga gbogbo wøn
b'øba p'ęgbęrun laiye, ønirisha ni baba wøn
b'obinrin ti pøto laiye, iwø motunrayo ni mø yan layo

ifę rę n'pa mi bi øti
oyi ifę rę n'kømi o mu mi lotutu
gbogbo ara mi ngbøn bi ęni w'ędo
b'oba føwø rę kanmi , arami aya gaga

ololufe mi apønbeepore
o'nfa øfun ni kij'ęran pe lęnu,
ohun mi k'in wa ę m'øya , irinajo niøję
nișęju ișęju løkan mi fa si ę

ololufęmi abęfę, ibadi aran awęlęwa
ęwa rę tan bi mønamana
otan kaari aiye, omu imøle wasayemi
ofimi løkan bale, aiya mi o ja ęru o si bamimø

ifę rę mumi rinri ajo ayø
omumi de ebute idunnu ati alafia
mowoke modupę løwø eledua
to semilanu nigba ti mo șe awari ifę rę

bi ewe ba pę Lara oșę, a ma d'øșę
ekurø lala b'aku ęwa
bi inu ba șè șì, aworan rę lowa ni bę.
iwø ni monifę julø .

mawo ariwo øja rara.
mașe da awøn ęlętan løhun
iru ifę wa yii lowu wøn
ifę at'oke l'atørun wa.
it's a poem. in my native language to my beloved sweetheart

— The End —