Submit your work, meet writers and drop the ads. Become a member
Tauhid May 2016
b'ęránko bà p'égbá nigbò, kiniun lolori wøn
b'ęiyę p'øgøfa l'ødan așa l'øga gbogbo wøn
b'øba p'ęgbęrun laiye, ønirisha ni baba wøn
b'obinrin ti pøto laiye, iwø motunrayo ni mø yan layo

ifę rę n'pa mi bi øti
oyi ifę rę n'kømi o mu mi lotutu
gbogbo ara mi ngbøn bi ęni w'ędo
b'oba føwø rę kanmi , arami aya gaga

ololufe mi apønbeepore
o'nfa øfun ni kij'ęran pe lęnu,
ohun mi k'in wa ę m'øya , irinajo niøję
nișęju ișęju løkan mi fa si ę

ololufęmi abęfę, ibadi aran awęlęwa
ęwa rę tan bi mønamana
otan kaari aiye, omu imøle wasayemi
ofimi løkan bale, aiya mi o ja ęru o si bamimø

ifę rę mumi rinri ajo ayø
omumi de ebute idunnu ati alafia
mowoke modupę løwø eledua
to semilanu nigba ti mo șe awari ifę rę

bi ewe ba pę Lara oșę, a ma d'øșę
ekurø lala b'aku ęwa
bi inu ba șè șì, aworan rę lowa ni bę.
iwø ni monifę julø .

mawo ariwo øja rara.
mașe da awøn ęlętan løhun
iru ifę wa yii lowu wøn
ifę at'oke l'atørun wa.
it's a poem. in my native language to my beloved sweetheart
Samuel Esther Aug 2022
Akingbade Ajasa
Okunrin merin oko Asabi
Omo kan sho sho Ajanaku
Omo omo Esugbade ilu dogun
You're a man greater than the gods

Akingbadesujoba you have dine with evil
Bi Akin pe oku ni popo, alaye a fohun
You'd rule the earth, let God hold his throne in heaven, your judgment is a man's last day.

Akin gbade odi oba
Akin wo igba ileke o joye
Akin wo lu o gba iyi
Akin se ti aiye odi oko oso, odi oko aje

Akin rola o gbagbe ewo
Akin roye o gbagbe iku
Akin robinrin gbagbe odale
Akin riyi o gbabge eledua to ni ayie lowo
The doom of a great man just begin
Writing poem with the mix of Yoruba is never easy.

— The End —