Hello Poetry
Submit your work and get some sparkles! Create free account
"aiye" poems
b'ęránko bà p'égbá nigbò, kiniun lolori wøn b'ęiyę p'øgøfa l'ødan așa l'øga gbogbo wøn b'øba p'ęgbęrun laiye, ønirisha ni baba wøn b'obinrin ti pøto laiye, iwø motunrayo ni mø yan layo ifę rę n'pa mi bi øti oyi ifę rę n'kømi o mu mi lotutu gbogbo ara mi ngbøn bi ęni w'ędo b'oba føwø rę kanmi , arami aya gaga ololufe mi apønbeepore o'nfa øfun ni kij'ęran pe lęnu, ohun mi k'in wa ę m'øya , irinajo niøję nișęju ișęju løkan mi fa si ę ololufęmi abęfę, ibadi aran awęlęwa ęwa rę tan bi mønamana otan kaari aiye, omu imøle wasayemi ofimi løkan bale, aiya mi o ja ęru o si bamimø ifę rę mumi rinri ajo ayø omumi de ebute idunnu ati alafia mowoke modupę løwø eledua to semilanu nigba ti mo șe awari ifę rę bi ewe ba pę Lara oșę, a ma d'øșę ekurø lala b'aku ęwa bi inu ba șè șì, aworan rę lowa ni bę. iwø ni monifę julø . mawo ariwo øja rara. mașe da awøn ęlętan løhun iru ifę wa yii lowu wøn ifę at'oke l'atørun wa.
0
May 15, 2016
May 15, 2016 at 5:42 PM UTC
ololufemi {my beloved }
Akingbade Ajasa Okunrin merin oko Asabi Omo kan sho sho Ajanaku Omo omo Esugbade ilu dogun You're a man greater than the gods Akingbadesujoba you have dine with evil Bi Akin pe oku ni popo, alaye a fohun You'd rule the earth, let God hold his throne in heaven, your judgment is a man's last day. Akin gbade odi oba Akin wo igba ileke o joye Akin wo lu o gba iyi Akin se ti aiye odi oko oso, odi oko aje Akin rola o gbagbe ewo Akin roye o gbagbe iku Akin robinrin gbagbe odale Akin riyi o gbabge eledua to ni ayie lowo The doom of a great man just begin
0
Aug 1, 2022
Aug 1, 2022 at 8:19 PM UTC
The fall of evill.
No going back We will defend our pride Our heritage Our fatherland Not with guns, powder nor machetes Not with armoured carriers But with powers ancestral We will visit Egungun Oya The god of divination We will invoke Mawu The god of the Sun and Moon Have you heard about Babalu aiye? The god of infectious diseases Let the games begin Omoluabi oooo! Omoluabi oh!! "Bo ba d'ogun; ko d'ogun" Where is Sango, the god of thunder? "Gunugu ni oruko, ti an pe Ifa?" "Okalamagbo ni oruko ti an pe awon Iya oshoronga" "Abiamo ki gbo ekun omo re", "Ki o ma ta si were" "Oya, Amotekun oooo" When the walls of Jericho fell How many bullets were shot? They stood on their father's faith How was Judah and Jerusalem taken? The red sea parted by the word We too, shall speak the word But now, the words our Ancestors When the centre can no longer hold Surely, things will fall apart "Omo Yoruba, ronu" Enough! No longer shall our lands be desecreted Cast the cowries in the calabash Let us inquire of our gods Shall we pursue and reclaim? Ready, set, "Amotekun dee" Babatunde Raimi Author/Life Coach/Poet 08178827380 & 08035063895
0
Jan 15, 2020
Jan 15, 2020 at 4:05 PM UTC
Amotekun